Muniratu (Live)-文本歌词

Muniratu (Live)-文本歌词

K1 De Ultimate
发行日期:

Muniratu ọmọ Àlàmú Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ Muniratu O kú ìnáwó ọjọ́un nílùú Canada o Tèmiladé, àwọn ọmọ Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ Àlàmú Bàbá dáadáa ló bí ẹ lọ́mọ Àlàmú adé Àlàmú, Àlàmú adé ọmọ t’Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ Muniratu bí a gbọ́ nílé pé wọ́n nà ẹ́ lóde àwa ti fọkàn balẹ Ọmọ Àlàmú Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ Ibi tí wọ́n gbé nà ẹ́ o ilẹ̀ á lanu á rojọ́ Muniratu ibi tí wọ́n gbé nà ẹ́ o( ilẹ̀ á lanu á rojọ́) Tèmiladé Sule Lèní o (a ó f’orò kó bá baba wọn, kó bá baba wọn o) (Lèní o, a ó forò kó bá baba wọn) Tèmiladé o ṣé ọjọ́ Muniratu mi nílùú Toronto, tẹ̀gbọ́n t’àbúrò ni gbogbo wọn Àwọn ọmọ Àlàmú adé mi Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ Muniratu o (Muniratu ) Ọmọ Àlàmú Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ (Muniratu) Tèmiladé ìwọ náà bọ́’bí Ọmọ t’Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ Àlàmú Muniratu mi (Muniratu mi) Sule, Àyìndé Arábámbí Hunter, Tèmiladé Tèmiladé ọmọ Àlàmú, ọ̀gá National Union ni Àlàmú o Owó National ni wọ́n fi bí wọn Ohun náà ni wọ́n fi kọ́ ẹ Muniratu mi (Muniratu mi) Àti Tèmiladé baby mi (Muniratu mi) Pẹ̀lú Sule (pẹ̀lú Sule Maito) Àwọn ọmọ Àlàmú Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ (Sule Maito) Bàbá dáadáa ló bí wa lọ́mọ (Sule Maito) Mumsy Muniratu Tèmiladé baby mi (Ọmọ Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ) Tèmiladé baby mi (Ọmọ Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ) Ọmọ Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ Àlàmú o Ọmọ Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ Àlàmú o Kí í kan kò mà ní ṣe ẹ́ o máa rìn máa yan fanda (Ọ̀tẹ́gbẹ̀yẹ Àlàmú o) Mumsy Munira, b’étí ẹ bá ń já ní Canada O kú Ìtọ́jú àwọn ọmọ Muniratu ní n kí ẹ Tèmiladé kí ló ń dún? (Orin wa ló ń dun) Kí ló ń kùn? (Ìlù wa ló ń kùn bí òjò) O dàgbà ọ̀jẹ̀ Olúayé Fújì (àwọn ìsín lelé o) Ètí inú Hunter Hunter mi (Hunter mi) Olúayé Fújì (Ọ̀gá wa o) Ọlọ́hun Ọba o ṣé lọ́dún tuntun ta bọ́sí Mustapha, ìjọba Èkó bí Kaaba ò bá wó Kò ní dá’rú Ọlọ́hun Ọba Bí kaaba ò bá wó, o ò ní wó lọ́lá Ọlọ́hun Ọba Àmín o Adékúnlé, Walimustapha O ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn mo kí ẹ kú ọdún Mustapha (Musitafa) Hunter má rìn jìnnà K1 De Ultimate (Adé orí ọ̀kín) Ẹni a bá torí ẹ̀ pa ẹdìẹ iwe ló ń jẹ Musitafa (Musitafa) Adékúnlé mo kí ẹ ò (Musitafa) Walimustapha mi SEGO mi Ẹni Ọlọ́hun bá gb’áyé lé lọ́wọ́ Ohun gbogbo tẹ́ ẹ rí yẹn àṣẹ Ọlọ́hun Ọba ni Àwa ẹ̀dá là ń ṣe Ọlọ́tọ̀ tó yatọ̀ o Mo wá ń bẹ̀ ẹ́ Ọlọ́hun Ọba Gbogbo dáadáa tó wà níbẹ̀ ni kẹ máa rí lójoojúmọ́ Aburú inú ẹ Ọlọ́hun má pin fún wa àmín àṣẹ Nǹkan tí mo bẹ̀rẹ̀ ni, kò ní tọwọ́ mi bàjẹ́ bó w’ọlá Ọlọ́hun Àmín o Musitafa (Musitafa) Adékúnlé ọmọ mi (Musitafa)